Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 3:23-25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

23. Nítòótọ́, asán ni ìbọ̀rìṣà àti ìrùkèrudò tí ó wà ní àwọn orí òkèkékèké àti àwọn òkè gíga;Nítòótọ́, nínú Olúwa Ọlọ́runwa ni ìgbàlà Ísírẹ́lì wà.

24. Láti ìgbà èwe wa ni àwọn òrìṣà ìtìjú tipa èso iṣẹ́ àwọn baba wa,ọ̀wọ́ ẹran wọn àti agbo ẹran wọn,ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin wọn.

25. Jẹ́ kí a dùbúlẹ̀ nínú ìtìjú wa,kí ìtìjú wa bò wá mọ́lẹ̀.A ti ṣẹ̀ sí Olúwa Ọlọ́run wa,àwa àti àwọn baba wa,láti ìgbà èwe wa títí di ònía kò gbọ́ràn sí Olúwa Ọlọ́run wa.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 3