Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 3:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítòótọ́, asán ni ìbọ̀rìṣà àti ìrùkèrudò tí ó wà ní àwọn orí òkèkékèké àti àwọn òkè gíga;Nítòótọ́, nínú Olúwa Ọlọ́runwa ni ìgbàlà Ísírẹ́lì wà.

Ka pipe ipin Jeremáyà 3

Wo Jeremáyà 3:23 ni o tọ