Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 3:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́ kí a dùbúlẹ̀ nínú ìtìjú wa,kí ìtìjú wa bò wá mọ́lẹ̀.A ti ṣẹ̀ sí Olúwa Ọlọ́run wa,àwa àti àwọn baba wa,láti ìgbà èwe wa títí di ònía kò gbọ́ràn sí Olúwa Ọlọ́run wa.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 3

Wo Jeremáyà 3:25 ni o tọ