Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 27:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

‘A ó mú wọn lọ sí ilẹ̀ Bábílónì, ní ibẹ̀ ni wọn ó sì wà títí di ìgbà tí mo bá padà,’ èyí ni ọ̀rọ̀ Olúwa. ‘Lẹ́yìn èyí, mà á mú wọn padà, Èmi yóò sì ṣe wọ́n lọ́jọ̀ ní ibí yìí.’ ”

Ka pipe ipin Jeremáyà 27

Wo Jeremáyà 27:22 ni o tọ