Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 27:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lóòótọ́, èyí ni ọ̀rọ̀ tí Olúwa àwọn ọmọ-ogun Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí nípa àwọn ohun ìṣúra tí ó ṣẹ́kù ní ilé Olúwa àti ní ààfin Ọba Júdà àti ní Jérúsálẹ́mù:

Ka pipe ipin Jeremáyà 27

Wo Jeremáyà 27:21 ni o tọ