Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 23:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí wòlíì tàbí àlùfáà tàbí ẹnikẹ́ni bá sì gbà wí pé, ‘Èyí ni ọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀ Olúwa.’ Èmi yóò fi ìyà jẹ ọkùnrin náà àti gbogbo agbo ilé rẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremáyà 23

Wo Jeremáyà 23:34 ni o tọ