Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 23:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni ohun tí ẹnìkọ̀ọ̀kan yín ń sọ fún ọ̀rẹ́ àti ará ilé rẹ̀: ‘Kí ni ìdáhùn Olúwa?’ tàbí ‘Kíni ohun tí Olúwa sọ?’

Ka pipe ipin Jeremáyà 23

Wo Jeremáyà 23:35 ni o tọ