Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 19:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Ní ibí yìí ni èmi yóò ti pa èrò Júdà àti Jérúsálẹ́mù run. Èmí yóò mú wọn ṣubú nípa idà níwájú àwọn ọ̀tá wọn, lọ́wọ́ àwọn tí ó ń wá ẹ̀mi wọn. Èmi yóò sì fi òkú wọn ṣe oúnjẹ fún àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run àti ẹranko ilẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremáyà 19

Wo Jeremáyà 19:7 ni o tọ