Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 15:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò jẹ́ kí àwọn opó wọn pọ̀ juyanrìn òkun lọ. Ní ọjọ́kanrí nièmi ó mú apanirun kọlu àwọnìyá ọmọkùnrin wọn. Lójìjì nièmi yóò mú ìfòyà àti ìbẹ̀rù bá wọn.

Ka pipe ipin Jeremáyà 15

Wo Jeremáyà 15:8 ni o tọ