Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 15:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi kò tún lè fi ìfẹ́ hàn si ọÈmi yóò fi atẹ fẹ́ wọn sí ẹnu ọ̀nàìlú náà. Èmi yóò mú ìsọ̀fọ̀ àti ìparunbá àwọn ènìyàn mi nítorí pé wọnkò tíì yí padà kúrò lọ́nà wọn.

Ka pipe ipin Jeremáyà 15

Wo Jeremáyà 15:7 ni o tọ