Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 15:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìyá ọlọ́mọ méje yóò dákú, yóòsì mí ìmí ìgbẹ̀yìn. Òòrùn rẹyóò wọ̀ lọ́sàn-án gangan, yóòdi ẹni ẹ̀tẹ́ òun àbùkù. Èmiyóò fi àwọn tí ó bá yè wá síwájúàwọn ọ̀tá wọn tí idà wà lọ́wọ́ wọn,”ni Olúwa wí.

Ka pipe ipin Jeremáyà 15

Wo Jeremáyà 15:9 ni o tọ