Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 7:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn ó dà fàdákà wọn sí ojú pópó, wúrà wọn ó sì dàbí èérí ìdọ̀tí fàdákà àti wúrà wọn kò ní le gbà wọ́n ní ọjọ́ ìbínú gbígbóná Olúwa. Wọn kò ní le jẹun tẹ́ ra wọn lọ́rùn tàbí kí wọn kún ikùn wọn pẹ̀lú oúnjẹ nítorí pé ó ti di ohun ìkọ̀sẹ̀ fún wọn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 7

Wo Ísíkẹ́lì 7:19 ni o tọ