Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 7:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn n ṣe ìgbéraga pẹ̀lú ohun ọ̀sọ́ wọn, tí ó lẹ́wà, wọn sì ti fi ṣe òrìṣà, wọn sì tún ya àwòrán ìríra wọn níbẹ̀. Nítorí náà, ní o sọ àwọn ǹnkan wọ̀nyí di ohun èérí tabi ìdọ̀tí fún wọn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 7

Wo Ísíkẹ́lì 7:20 ni o tọ