Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 6:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo ibi tí ẹ ń gbé àti àwọn ibi gíga yín ni yóò di píparun, gbogbo pẹpẹ yín ni yóò di ahoro, àwọn òrìṣà yín yóò di fífọ́ túútúú, àwọn pẹpẹ tùràrí yín ni a ó gé lulẹ̀, gbogbo iṣẹ́ yín yóò parẹ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 6

Wo Ísíkẹ́lì 6:6 ni o tọ