Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 6:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

N ó tẹ́ òkú àwọn ará Ísírẹ́lì síwájú òrìsà wọn n ó sì fọ́n egungun wọn yí pẹpẹ wọn ká.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 6

Wo Ísíkẹ́lì 6:5 ni o tọ