Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 43:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

tí ojú gbogbo ohun tí wọn ti ṣe bá tì wọ́n, jẹ́ kí wọ́n mọ̀ àwòrán ilé Ọlọ́run náà bí wọ́n ṣe tò ó lẹ́sẹẹsẹ, àbájáde àti àbáwọlé rẹ̀ gbogbo àwòrán àti gbogbo òfin àti ìlànà rẹ̀. Kọ ìwọ̀nyí sílẹ̀ ní iwájú wọn kí wọn kí ó lè jẹ́ olóòtọ́ si àwòrán rẹ̀, kí wọ́n sì tẹ̀lé gbogbo òfin rẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 43

Wo Ísíkẹ́lì 43:11 ni o tọ