Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 43:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èyí yìí ní òfin ilé Ọlọ́run náà: Gbogbo àyíká lórí òkè gíga ní yóò jẹ́ ibi mímọ́ jùlọ. Bí èyí ni òfin tẹ́ḿpìlì náà.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 43

Wo Ísíkẹ́lì 43:12 ni o tọ