Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 40:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn náà ni ó wá lọ sí ẹnu ọ̀nà òde tí ó kọjú sí ìlà òòrùn. Ó gun àtẹ̀gùn rẹ̀, o sì wọn ìloro ẹnu ọ̀nà ilé; ó jẹ́ ọ̀pa kan ní jíjìn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 40

Wo Ísíkẹ́lì 40:6 ni o tọ