Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 40:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo rí ògiri tí ó yí agbègbè ibi mímọ̀ po. Gígùn ọ̀pá ìwọnlẹ̀ tí ó wà ní ọwọ́ ọkùnrin náà sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́fà, ọkọ̀ọ̀kan sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan àti ilásì mẹ́rin ẹsẹ̀ bàtà. Ó wọn ògiri náà; ó jẹ́ ìwọ̀nyí ọ̀pá náà ni níní ipọn, ó sì jẹ́ ọ̀pá kan ní gíga.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 40

Wo Ísíkẹ́lì 40:5 ni o tọ