Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 40:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yàrá kéékèèkéé sì jẹ ọ̀pá kan ni gígùn àti ọpá kan ní ibú, ìgbéró ògiri àárin yàrá kéékèèkéé náà jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ márùn-ún ni nínípọn. Ìloro ẹnu ọ̀nà náà tí ó kángun sí àtẹ̀wọ́ ẹnu ọ̀nà náà tó kọjú sì tẹ́ḿpìlì jẹ́ ọ̀pá kan ní jíjìn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 40

Wo Ísíkẹ́lì 40:7 ni o tọ