Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 40:49 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àtẹ̀wọ̀ ẹnu ọ̀nà jẹ́ ogún ìgbọ̀nwọ́ ní fífẹ̀, àti ìgbọ̀nwọ́ méjìlá láti iwájú dé ẹ̀yìn. Láti ara àtẹ̀gùn ní a ti ń dé ibẹ̀ àwọn òpó sì wà ni ẹ̀gbẹ́ kọ̀ọ̀kan àwọn àtẹ́rígbà náà.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 40

Wo Ísíkẹ́lì 40:49 ni o tọ