Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 40:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó mú mi lọ sí àtẹ̀wọ̀ ẹnu ọ̀nà tẹ́ḿpìlì, ó sì wọn àwọn àtẹrígbà àtẹ̀wọ̀ ẹnu ọ̀nà; wọ́n jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ márùn ún ní fífẹ̀, ẹ̀gbẹ́ méjèèjì rẹ̀. Fífẹ̀ àbáwọlé jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́rìnlá, ìgbéró àwọn ògiri náà jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́ta ní fífẹ̀ ní ẹ̀gbẹ́ méjèèjì.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 40

Wo Ísíkẹ́lì 40:48 ni o tọ