Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 40:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn yàrá kéékèèkéé rẹ̀, ìgbéró ògiri rẹ̀ àti àtẹ̀wọ̀ ẹnu ọ̀nà rẹ̀ ní ìwọ̀n kan náà pẹ̀lú àwọn tí ó kù. Ẹnu ọ̀nà náà àti àtẹ̀wọ̀ ẹnu ọ̀nà ni ihò yí po. Ó jẹ́ àádọ́ta ìgbọ̀nwọ́ ni fífẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 40

Wo Ísíkẹ́lì 40:33 ni o tọ