Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 40:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àtẹ̀wọ̀ ẹnu ọ̀nà rẹ̀ dojúkọ àgbàlá tí ìta; àwọn igi ọ̀pẹ ṣe ọ̀sọ́ sí àtẹ́rígbà ní ẹ̀gbẹ́ méjèèjì, àtẹ̀gùn mẹ́jọ sì lọ sókè rẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 40

Wo Ísíkẹ́lì 40:34 ni o tọ