Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 40:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn náà ó mú mi lọ sí ojú òde àgbàlá. Níbẹ̀ mo rí yàrá díẹ̀ àti pèpéle tí a kọ́ yí àgbàlá ká; ọgbọ̀n yàrá wà lẹ́gbẹ̀ pèpéle náà,

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 40

Wo Ísíkẹ́lì 40:17 ni o tọ