Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 40:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

O ṣe ààlà sí ẹ̀gbẹ́ àwọn ẹnu ọ̀nà, ìbú rẹ̀ sì jẹ́ bákan náà pẹ̀lú gígun rẹ̀: èyí jẹ́ pèpéle tí ìsàlẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 40

Wo Ísíkẹ́lì 40:18 ni o tọ