Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 39:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí mo ti mú wọn padà kúrò ní àwọn orílẹ̀ èdè, tí mo sì kó wọn jọ pọ̀ kúrò ni ìlú àwọn ọ̀tá wọn, èmi yóò fi ara mi hàn ni mímọ́ nípasẹ̀ wọn ní ojú àwọn orílẹ̀ èdè púpọ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 39

Wo Ísíkẹ́lì 39:27 ni o tọ