Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 39:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn yóò gbàgbé ìtìjú wọn àti gbogbo àìsòdodo tí wọ́n fihàn sí mi nígbà tí wọn ń gbé ni àìléwu ni ilẹ̀ wọn níbi tí kò ti sí ẹnìkẹ́ni láti dẹ́rù bà wọ́n.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 39

Wo Ísíkẹ́lì 39:26 ni o tọ