Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 39:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn kò ní nílo láti kó igi jọ láti inú pápá, tàbí gé e láti inú igbó, nítorí pé wọ́n yóò lé òhun ìjà ogun bi epo ìdáná. Wọn yóò sì kógun àwọn tí ó ṣe ìgárá sí wọn, wọn yóò sì bo ilé àwọn tí ó bo ilé wọn, ni Olúwa Ọba tẹnumọ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 39

Wo Ísíkẹ́lì 39:10 ni o tọ