Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 39:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Ní ọjọ́ náà èmi yóò sì fi ibi ìsìnkú fún Gógì ní Ísírẹ́lì, ni àfonífojì àwọn ti ó rìn ìrìnàjò lọ sí agbègbè ilà òòrùn òkun. Yóò di ojú ọ̀nà àwọn arìnrìn àjò, nítorí Gógì àti gbogbo ìjọ rẹ̀ ni àwa yóò sin síbẹ̀. Nítorí náà, a óò pè é ní àfonífojì tí Ámónì Gógì.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 39

Wo Ísíkẹ́lì 39:11 ni o tọ