Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 37:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò ṣe wọ́n ní orílẹ̀ èdè kan ní ilẹ̀ náà, ní orí òkè Ísírẹ́lì, Ọba kan ni yóò wà lórí gbogbo wọn, wọn kì yóò sì jẹ́ orílẹ̀ èdè méjì mọ́, tàbí kí a pín wọn sí ìjọba méjì.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 37

Wo Ísíkẹ́lì 37:22 ni o tọ