Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 37:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kí ó sì sọ fún wọn pé, ‘Èyí yìí ni ohun tí Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí: Èmi yóò mú Ísírẹ́lì jáde kúrò ní àwọn orílẹ̀ èdè tí wọ́n ti lọ. Èmi yóò ṣà wọ́n jọ pọ̀ láti gbogbo agbègbè, èmi yóò sì mú wọn padà sí ilẹ̀ ara wọn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 37

Wo Ísíkẹ́lì 37:21 ni o tọ