Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 35:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí pé ìwọ ń yọ̀ nígbà tí ìní ilé Ísírẹ́lì di ahoro, bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni èmi yóò ṣe hùwà sí ọ. Ìwọ yóò di ahoro, ìwọ òkè Séírì, ìwọ àti gbogbo ará Édómù. Nígbà náà, wọn yóò mọ̀ pé, èmi ni Olúwa.’ ”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 35

Wo Ísíkẹ́lì 35:15 ni o tọ