Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 35:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni ìwọ yóò mọ̀ pé èmi Olúwa ti gbọ gbogbo ohun ẹ̀gàn tí ìwọ ti sọ lòdì sí àwọn òkè Ísírẹ́lì náà. Ìwọ wí pé, “A ti fi wọ́n sílẹ̀ ní ṣíṣọ̀fọ̀, a sì fi fún wa láti pajẹ.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 35

Wo Ísíkẹ́lì 35:12 ni o tọ