Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 35:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nítorí náà níwọ̀n ìgbà tí mo ti wà láàyè, ní Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí, èmi yóò hùwà sí ọ ní ìbámu pẹ̀lú ìbínú àti owú tí o fihàn nínú ìkórìíra rẹ sí wọn, èmi yóò fi ara mi hàn ní àárin wọn, nígbà tí mo bá ṣe ìdájọ́ rẹ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 35

Wo Ísíkẹ́lì 35:11 ni o tọ