Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 33:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣọ fún wọn pé, ‘Níwọ̀n ìgbà tí mo wà láàyè ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí, èmi kò ní inú dídùn sí ikú ènìyàn búburú, ṣùgbọ́n dípò bẹ́ẹ̀, kí wọ̀nyí padà kúrò ní ọ̀nà wọn gbogbo kì wọn kì ó sì yè. Yí! Yípadà kúrò ni ọ̀nà búburú gbogbo! Kí ló dé tí ìwọ yóò kú Áà! Ísírẹ́lì?’

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 33

Wo Ísíkẹ́lì 33:11 ni o tọ