Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 33:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí náà, ọmọ ènìyàn, sọ fún àwọn ènìyàn ilẹ̀ rẹ, ‘Ìsòdodo ti olódodo ènìyàn kì yóò gbà á nígbà tí òun bá ṣe àìgbọ́ràn, ìwà búburú ènìyàn búburú kì yóò mú kí o ṣubú nígbà tí ó bá yí padà kúrò nínú rẹ̀. Bí olódodo ènìyàn bá ṣẹ̀, a kò ni jẹ́ kí ó yè nítorí òdodo rẹ̀ ti tẹ́lẹ̀.’

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 33

Wo Ísíkẹ́lì 33:12 ni o tọ