Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 30:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò mú kí apá Ọba Bábílónì lé, ṣùgbọ́n apá Fáráò yóò sì rọ. Nígbà náà wọn yóò mọ̀ pé Èmi ni Olúwa, nígbà tí mo bá mú idà mi sí ọwọ́ Ọba Bábílónì yóò sì fí idà náà kọlu Éjíbítì.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 30

Wo Ísíkẹ́lì 30:25 ni o tọ