Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 30:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò mú kí apá Ọba Bábílónì ní agbára, èmi yóò sì fi idà mi sí ọwọ́ rẹ, ṣùgbọ́n èmi yóò ṣẹ́ apá Fáráò, yóò sì kérora níwájú rẹ̀ bí ọkùnrin tí a ṣá ní àṣápa.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 30

Wo Ísíkẹ́lì 30:24 ni o tọ