Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 30:13-15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

13. “ ‘Báyìí ní Olúwa Ọlọ́run wí:“ ‘Èmi yóò pa àwọn òrìṣà runÈmi yóò sì mú kí òpin dé báère òrìṣà gbígbẹ́ ni Nófìkò ní sí ọmọ aládé mọ́ ní Éjíbítì,Èmi yóò mú kí ìbẹ̀rù gba gbogbo ilẹ̀ náà.

14. Èmi yóò sì mú kí Pátírọ́sì di ahoroèmi yóò fi ina sí Sóánìèmi yóò sì fi ìyà jẹ Tébésì

15. Èmi yóò tú ìbínú mi jáde sórí Pélúsíómùìlú odi Éjíbítìèmi yóò sì ké àkójọpọ̀ Jépésì kúrò

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 30