Èmi yóò mú kí àwọn odò Náílì gbẹÈmi yóò sì ta ilẹ náà fún àwọn ènìyàn búburú:láti ọwọ́ àwọn àjòjì ènìyànÈmi yóò jẹ́ kí ilẹ̀ náà àti gbogbo ohun tí ó wá nínú rẹ ṣòfò.Èmi Olúwa ni ó ti sọ ọ́.