Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 30:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun àti àwọn ológun rẹ̀ẹ́rù àwọn orílẹ̀-èdèní a o mú wá láti pa ilẹ náà run.Wọn yóò fa idà wọn yọ sí Éjíbítìilẹ̀ náà yóò sì kún fún àwọn tí a pa.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 30

Wo Ísíkẹ́lì 30:11 ni o tọ