Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 27:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Àwọn ará Árábù àti gbogbo àwọn ọmọ aládé Kédárì àwọn ni àwọn onibárà rẹ: ní ti ọ̀dọ́ àgùntàn, àgbò àti ewúrẹ́, nínú ìwọ̀nyí ni wọ́n ti jẹ́ oníbárà rẹ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 27

Wo Ísíkẹ́lì 27:21 ni o tọ