Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 23:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nítorí wọn ti dá ẹ̀ṣẹ̀ panṣágà ẹ̀jẹ̀ sì wà ní ọwọ́ wọn. Wọn dá ẹ̀ṣẹ̀ panṣágà pẹ̀lú àwọn orìṣà wọn; kódà wọ́n fi àwọn ọmọ wọn tí wọn bí fúnni ṣe ìrúbọ, gẹ́gẹ́ bí oúnjẹ fún wọn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 23

Wo Ísíkẹ́lì 23:37 ni o tọ