Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 23:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bákan náà ni wọ́n ti ṣe èyí náà sí mi: Ní àkókò kan náà wọn ba ibi mímọ́ mi jẹ́, wọ́n sì lo ọjọ́ ìsinmi mi ní àìmọ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 23

Wo Ísíkẹ́lì 23:38 ni o tọ