Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 20:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Síbẹ̀síbẹ̀ mo wò wọ́n pẹ̀lú àánú, ń kò sì pa wọ́n run tàbí kí òpin dé bá wọn nínú ihà.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 20

Wo Ísíkẹ́lì 20:17 ni o tọ