Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 20:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí pé wọn kọ òfin mi sílẹ̀, wọn kò sì tẹ̀lé àsẹ mi, wọn sọ ọjọ́ ìsinmi mi dí aláìmọ́. Nítorí pé tọkàntọkàn ni wọn ń tẹ̀lé òrìṣà wọn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 20

Wo Ísíkẹ́lì 20:16 ni o tọ