Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 16:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nítorí náà, Èmi yóò ṣa gbogbo àwọn olólùfẹ́ rẹ jọ, pẹ̀lú gbogbo àwọn ti ẹ jọ ṣe fàájì, àwọn tí ìwọ fẹ́ àti àwọn tí ìwọ korìíra. Èmi yóò ṣa gbogbo wọn káàkiri, láti mú wọn lòdì sí ọ, èmi yóò sí aṣọ rẹ, níwájú wọn, wọn yóò sì rí ìhòòhò rẹ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 16

Wo Ísíkẹ́lì 16:37 ni o tọ