Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 16:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò dá ọ lẹ́jọ́, gẹ́gẹ́ bí a ti dá obìnrin tó ba ìgbeyàwó jẹ́, tí wọn sì ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀; Èmi yóò sì mú ẹ̀jẹ̀ ìbínú àti owú mi wá sórí rẹ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 16

Wo Ísíkẹ́lì 16:38 ni o tọ