Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 15:6-8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

6. “Nítorí náà, báyìí ni Olúwa Ọlọ́run wí: Bí mo ṣe sọ igi àjàrà tó wà láàrin àwọn igi inú igbó yóòkù di igi ìdáná, bẹ́ẹ̀ ni Èmi yóò ṣe ṣe gbogbo ènìyàn tó ń gbé Jérúsálẹ́mù.

7. Èmi yóò dojúkọ wọ́n. Bó tilẹ̀ jẹ́ pé wọn ti jáde kúrò nínú iná kan síbẹ̀ iná mìíràn yóò pàpà jó wọn. Nígbà tí mo bá sì dojúkọ wọ́n, ẹ ó sì mọ̀ pé Èmi ni Olúwa.

8. Èmi yóò sọ ilé náà di ahoro nítorí ìwà àìsòótọ́ wọn, ni Olúwa Ọlọ́run wí.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 15